in ,

LoveLove

Zuck

What do you think?

Newbie

Written by Hsmcoco

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

GIPHY App Key not set. Please check settings

    Hehehe

    Topic : Olorun olododo ki o busi fun o. Part 2 Psalms 115:10-16 [10]Ara-ile Aaroni, gbẹkẹle Oluwa, on ni iranlọwọ wọn ati asà wọn. O house of Aaron, trust in the LORD: he is their help and their shield. [11]Ẹnyin ti o bẹ̀ru Oluwa, gbẹkẹle Oluwa: on ni iranlọwọ wọn ati asà wọn. Ye that fear the LORD, trust in the LORD: he is their help and their shield. [12]Oluwa ti nṣe iranti wa: yio bùsi i fun wa: yio bùsi i fun ara-ile Israeli; yio bùsi i fun ara-ile Aaroni. The LORD hath been mindful of us: he will bless us; he will bless the house of Israel; he will bless the house of Aaron. [13]Yio bùsi i fun awọn ti o bẹ̀ru Oluwa, ati ewe ati àgba. He will bless them that fear the LORD, both small and great. [14]Oluwa yio mu nyin bisi i siwaju ati siwaju, ẹnyin ati awọn ọmọ nyin. The LORD shall increase you more and more, you and your children. [15]Ẹnyin li ẹni-ibukún Oluwa, ti o da ọrun on aiye. Ye are blessed of the LORD which made heaven and earth. [16]Ọrun ani ọrun ni ti Oluwa; ṣug