in

*IṢẸ IRANṢẸ TI ỌRỌ IṢỌTẸLẸ NÌNU ISIN ỌJỌ ISEGUN (TUESDAY)TI IPEJỌPỌ MÌMỌ TI AYIKA LAWNA ATI TI ÒRÌLE-EDE SI ORÍLẸ ÉDÉ IKÉJÍDÍNLAAADOTA IRU RẸ NÌ ÓJÓ IKEFA OSU KẸJỌ ODUN EGBAA OLEMERINLÈLOGUN (6/8/2024) LATI ENU OLUSO AGUNTAN N.O.T. AKINTOLA (WOLI IGBIMO ALASE/ WOLI IPINLE AGEGE).* Bayi ni Oluwa yin wi, Oluwa ati Olorun yin eniti o ngba ija awon eniyan Re ja, e woo, Mo ti gba kuro lowo yin, Mo ti gba kuro lowo yin igbe ti iberu ati ti eru, e ki yio gburo re Mo, beni e ki yio tun wonu re mo, sugbon Emi yio gbe si owo awon to npon yin loju, awon ti won ti so wipe e dobale ki awon ba le rin koja lori yin ni Oluwa wi. Emi ti nso fun yin awon ifihan ati ti iran ti o jinle nipa orile ede yin lati ibere ipejopo mimo yii. E woo, Emi nsi oju iwe miran nipa ti orile ede yii lowuro yii, orile ede ti e wa ninu re. Obinrin eyiti nse ogbologbo lojo ori yio loyun yio si bi awon omo. Ni akoko ti yio marobi, eje yio ma ya nitoripe o nmurasile lati bimo. Si eyin eniyan Mi, eyin ki yio wa ninu okunkun

What do you think?

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

GIPHY App Key not set. Please check settings

    I don’t have ABS or orgasmic shoulder muscles but I have a Heart that will treat you right.

    If you want to know your past, look into your present conditions. If you want to know your future, look into your present actions.