in

Prayer

Emi o se ohun titun  

Part 2

Isaiah 43:4-7

[4]Niwọn bi iwọ ti ṣe iyebiye to loju mi, ti iwọ ṣe ọlọla, emi si ti fẹ ọ: nitorina emi o fi enia rọpò rẹ, ati enia dipo ẹmi rẹ.

Since thou wast precious in my sight, thou hast been honourable, and I have loved thee: therefore will I give men for thee, and people for thy life.

[5]Má bẹ̀ru: nitori emi wà pẹlu rẹ; emi o mu iru-ọmọ rẹ lati ìla-õrun wá, emi o si ṣà ọ jọ lati ìwọ-õrun wá.

Fear not: for I am with thee: I will bring thy seed from the east, and gather thee from the west;

[6]Emi o wi fun ariwa pe, Da silẹ; ati fun gusu pe, Máṣe da duro; mu awọn ọmọ mi ọkunrin lati okere wá, ati awọn ọmọ mi obinrin lati opin ilẹ wá.

I will say to the north, Give up; and to the south, Keep not back: bring my sons from far, and my daughters from the ends of the earth;

[7]Olukuluku ẹniti a npè li orukọ mi: nitori mo ti dá a fun ogo mi, mo ti mọ ọ, ani, mo ti ṣe e pé.

Even every one that is called by my name: for I have created him for my glory, I have formed him; yea, I have made him.

Prayer points Ete Owo Adura

  (1)  Alatunto ohun gbogbo, yio tun aye re to si rere.

 (2) Oluwa yio ba awon ota re ja, yio si gba O la lowo Ogun awon Ota re.

 (3) Eyin Ole emi, ohun rere gbogbo ti o ti ko lo lara mi, e da pada ni oruko Jesu.  

 (4) Tani o gbe Koto Iku fun mi ati ebi, ati Iwo ati Ile ti o kanju fun eje ki o pe sodo won do ni oruko Jesu.

 (5) Angeli iba pa Balamu mo ogiri bikose aanu to ri gba, Balamu aye iwo atemi yio ri ibinu angeli Olorun.

(6) Ofa ti o nso  abiyamo di agan ojo ale , ni oruko Jesu ko ni ba o.

(7) ile ti mo te yi,  ma so eso Ogo fun mi ni ojojumo aye mi.

  Pastor Fagbamigbe cares

  Do-Wonder international

  07035011971

What do you think?

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

GIPHY App Key not set. Please check settings

    Making money mood

    : THE SWORD OF THE SPIRIT