in

Topic :Iranlowo Olorun si gbogbo eniyan. Psalm 121:1-4 [1]EMI o gbé oju mi si ori oke wọnnì, nibo ni iranlọwọ mi yio ti nwa? I will lift up mine eyes unto the hills, from whence cometh my help. [2]Iranlọwọ mi yio ti ọwọ Oluwa wá, ti o da ọrun on aiye. My help cometh from the LORD, which made heaven and earth. [3]On kì yio jẹ́ ki ẹsẹ rẹ ki o yẹ̀; ẹniti npa ọ mọ́ kì yio tõgbe. He will not suffer thy foot to be moved: he that keepeth thee will not slumber. [4]Kiyesi i, ẹniti npa Israeli mọ́, kì itõgbe, bẹ̃ni kì isùn. Behold, he that keepeth Israel shall neither slumber nor sleep. Prayer Points (1) Akaba Ogo ti e o fi goke de ibi giga, Oluwa ko gbe kale si iwaju re. (2) Olorun Anu fi Anu re gbe mi Jade togo_ togo ninu yara okunkun idile ti Ogun fi O mi pamo si ni oruko Jesu Kristi Oluwa wa. (3) Omo eleran re, ko ni pada je egungun, e o ni ba won pa itan Oro ninu osi. (4) Ona ti o ma gba de ibi Ogo ati aseyori nla re, ko ni di pinpin O. (5) E o ni jabo nibiti won ti nret

What do you think?

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

GIPHY App Key not set. Please check settings

    For Gos to hear you

    *HAPPY BIRTHDAY TO THE WHOLE WORLD….. 💁🏻‍♂️Everyone is 2024 today* Do you know that today the whole world is of the same age.! Today is a very special day and comes once every one thousand (1,000) years. Your age + Your Year of birth, Everyone = 2024 It is so strange that even experts cannot explain it.! You should check it out and see that it is 2024. Been waiting for thousands of years! Example: My age is 37. I was born in the year 1987. So 37+1987= 2024 Use your age this year. Example: I was born in 1951 and I am 73 years old. 1951 +73=2024 🙋🏻‍♂️Very interesting.. Try it. 😊