Topic : Olorun ki o fi O le oloore eniyan lowo .
Tex t: Psalms 22:6-11
[6]Ṣugbọn kòkoro li emi, kì isi iṣe enia; ẹ̀gan awọn enia, ati ẹlẹya awọn enia.
But I am a worm, and no man; a reproach of men, and despised of the people.
[7]Gbogbo awọn ti o ri mi nfi mi rẹrin ẹlẹya: nwọn nyọ ṣuti ète wọn, nwọn nmì ori pe,
All they that see me laugh me to scorn: they shoot out the lip, they shake the head, saying,
[8]Jẹ́ ki o gbẹkẹle Oluwa, on o gbà a là; jẹ ki o gbà a là nitori inu rẹ̀ dùn si i.
He trusted on the LORD that he would deliver him: let him deliver him, seeing he delighted in him.
[9]Ṣugbọn iwọ li ẹniti o mu mi jade lati inu wá: iwọ li o mu mi wà li ailewu, nigbati mo rọ̀ mọ́ ọmu iya mi.
But thou art he that took me out of the womb: thou didst make me hope when I was upon my mother’s breasts.
[10]Iwọ li a ti fi mi le lọwọ lati inu iya mi wá: iwọ li Ọlọrun mi lati inu iya mi wá.
I was cast upon thee from the womb: thou art my God from my mother’s belly.
[11]Máṣe jina si mi; nitori ti iyọnu sunmọ etile; nitoriti kò si oluranlọwọ.
Be not far from me; for trouble is near; for there is none to help.
Prayer Points – Adura gbigba
(1) Aanu a soro lori ayé re loni
(2) lo ri iye Olorun gba nibi gbogbo ti o ba de.
(3) Psalms 22: 10 wipe ” iwo ni a fi mi le lowo”, ma je ki ogun eniyan ja mi gba lowo Re.
(4) Oluwa gba mi lowo eniyan ti fi mi le lowo , ti ki se Iwo.
(5) Olori ogun ti o pon O loju, Olorun yan ibon fun won.
(6) ilẹkun aanu Olorun ko ni ti mo O.
(7) Ibi ti baba ati iya ko de aanu gbe O de i
Good morning this morning